CERN
Ìrísí
Coordinates: 46°14′03″N 6°03′10″E / 46.23417°N 6.05278°E
| European Organization for Nuclear Research Organisation européenne pour la recherche nucléaire | ||
|---|---|---|
Àwọn orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ | ||
| Ìdásílẹ̀ | 29 September 1954[1] | |
| Ibùjókòó | Geneva, Switzerland | |
| Ọmọẹgbẹ́ | Àwọn orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ 21 àti abẹ̀wò 7 | |
| Olùdarí Àgbà | Fabiola Gianotti | |
| Website | cern.ch | |
The 12 founding member states of CERN in 1954 a[›] (map borders from 1989) |
54 years after its foundation, membership to CERN increased to 20 states, 18 of which are also EU members in 2010 |
CERN tàbí European Organization for Nuclear Research (Faransé: Organisation européenne pour la recherche nucléaire), lasan bi CERN tabi Cern (
/ˈsɝn/; ìpè Faransé: [sɛʁn]; e wo Ìtàn) jẹ́ àgbájọ akáríayé tí iṣẹ́ rẹ̀ ni láti bòjúsí ìṣeṣẹ́ ilé-àdánwò físíksì eruku tóbijùlọ lágbàáyé, tó wà ní àríwáìwọ̀òrùn àdúgbò Geneva ní ẹ̀bá bodè Fránsì àti Swítsàlandì (46°14′3″N 6°3′19″E / 46.23417°N 6.05528°E). Ó jé dídásílẹ̀ ní 1954, àgbájọ náà ní orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ Europe 20.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>tag; no text was provided for refs namedfoundation