Jump to content

Simple Mail Transfer Protocol

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Simple Mail Transfer Protocol (SMTP) jẹ́ protokolu internet fún ìfiránsẹ́ lẹ́tà oníná (e-mail). Àlàyé rẹ̀ wà nínú ìwé RFC821 àti RFC1123. Protokolu tí à n lò lọ́wọ́ bayi jẹ́ àfikún mọ́ protokolu àkọ́kọ́ tí àlàyé rẹ̀ wà nínú ìwe RFC 2821.


Ìtàn