Jump to content

Simple Mail Transfer Protocol

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Simple Mail Transfer Protocol (SMTP) jẹ́ protokolu internet fún ìfiránsẹ́ lẹ́tà oníná. Àlàyé rẹ̀ wà nínú ìwé RFC821 àti RFC1123. Protokolu tí à n lò lọ́wọ́ bayi jẹ́ àfikún mọ́ protokolu àkọ́kọ́ tí àlàyé rẹ̀ wà nínú ìwe RFC 2821.


Ìtàn